Skip to main content
Showing posts with the label FI IYIN FUN JESU OLURAPADA WA

FI IYIN FUN JESU OLURAPADA WA

Fi iyin fun Jesu, Olurapada wa, Ki aye k’okiki ife Re nla ; Fi iyin fun ! eyin Angeli ologo, F’ola at’ogo fun oruko re, B’olu’agutan, Jesu y’o to omo Re L’apa Re l’o ngbe won le l’ojojo Eyin eniyan mimo ti ngb’oke Sion Fi iyin fun pelu orin ayo Fi iyin fun, Jesu Olurapada wa, Fun wa, …

© 2020 GospelHub

Designed by Open Themes & Nahuatl.mx.